Anfani ti Asa ati Ise Yoruba ni lori Coronavirus

Baba Asa ati lse, Asiwaju Olu Mayungbe tun gbe aditu oro wa si ori ayelujara ‘youTube’ nipa ipa ti awon oogùn Youruba ni lori ‘Coronavirus’. Inu asa ati ise wa ni abayori aisan ti awon ota wa da si’ta fun omo araye. Awon Baba wa layelaye ti se ise sile fun wa lati bori ajakale aisan irisirisi. Ki’wa ni isoro wa, ti a nreti awon Oyinbo alawo fun fun ti won k o ni’fe wa? E ma ba mi kalo ni sise ntele. Ire o. Coronavirus yi ko ni do wa mo eru lo o….. Please subscribe to our YouTube channel

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *