The illustrious Sons & Daughters of Oduduwa

You are welcome home

‘ÈTÒ ÌDÁNILÓLÁ KÁRO OJIRE OMO OODUA’ Ceremony is the first of its kind award to be held in 2020, August 1st in lbadan, Oyo State. It will be a day of celebration to gather and recognize those who had helped and those who are still helping Yoruba people to create a new world and a future for the Yoruba race. without saying Yoruba will never unite , love each other or progress- whether it’s by building awareness of Yoruba language, cultural awareness, spirituality , commerce and industry, inspiring and empowering others to take positive action , or advocating for those who need support. “Alone we can do so little; together we can do much.”

KOOOF: Karo-Ojire Omo Oodua Foundation is a Hall of Fame that will be recognizing and honoring those who have contributed to the sustainability of Yoruba culture as a way to immortalize them and encourage the present and future generations to do better annually.

Ayeye ETO Idanilola ti Kaaro OJIIRE OMO ODUA FOUNDATION akoko iru re ti yoo waye ni inu osu Ogun, odun 2020 ti a wa yi ni ilu Ibadan, Ipinle Oyo ni yoo je ojo kan ara oto lati se akojo ohun mimo riri awon akoni ti won ti fi gbogbo ilaagun won sin Ile Yoruba ati awon ti won si n se ise takun-takun lati mu isokan, ife ohun ilosiwaju ile Yoruba duro sinsin.

Yala, nipa eto Oro aje, igbega asa ati ise, ise ona, eto eko, imo ero ati sayensi, ere idaraya, fifa ara eni l’owo s’oke ati riran awon ti o ku die kiato fun l’owo.

“Se agbajowo la fi n s’oya, ajeje owo kan o gberu d’ori” igi kan o si lee da Igbo se….

Kaaro OJIIRE OMO ODUA FOUNDATION je gbongan ayesi ti yoo maa se afihan ati mo riri awon akoni ti won ti sa gbogbo ipa won lati mu iyi ati ogo ba Asa ati Ise ile Yoruba lai sinmi lai s’aare….

Eyi je ona kan gbogi lati ri wipe oruko awon akoni wonyi ko parun, ti yoo si lee maa je koriya fun awon Iran iwoyi ati Iran ti n bo lona ki awon naa o lee see ise takun-takun ju ti ateyinwa lati gbe Iran Yoruba gun Oke Agba.